Hébérù 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí Ọlọ́run kì í ṣe aláìṣòdodo tó fi máa gbàgbé iṣẹ́ yín àti ìfẹ́ tí ẹ fi hàn fún orúkọ rẹ̀ + bí ẹ ṣe ń ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn ẹni mímọ́, tí ẹ sì ń bá a lọ láti ṣe ìránṣẹ́. Jémíìsì 2:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Bákan náà, ṣebí àwọn iṣẹ́ ló mú kí á ka Ráhábù aṣẹ́wó pẹ̀lú sí olódodo, lẹ́yìn tó gba àwọn òjíṣẹ́ lálejò, tó sì ní kí wọ́n gba ọ̀nà míì jáde?+
10 Torí Ọlọ́run kì í ṣe aláìṣòdodo tó fi máa gbàgbé iṣẹ́ yín àti ìfẹ́ tí ẹ fi hàn fún orúkọ rẹ̀ + bí ẹ ṣe ń ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn ẹni mímọ́, tí ẹ sì ń bá a lọ láti ṣe ìránṣẹ́.
25 Bákan náà, ṣebí àwọn iṣẹ́ ló mú kí á ka Ráhábù aṣẹ́wó pẹ̀lú sí olódodo, lẹ́yìn tó gba àwọn òjíṣẹ́ lálejò, tó sì ní kí wọ́n gba ọ̀nà míì jáde?+