-
Jóṣúà 8:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ohun tí o ṣe sí Jẹ́ríkò àti ọba rẹ̀ gẹ́lẹ́ ni kí o ṣe sí Áì àti ọba rẹ̀,+ àmọ́ ẹ lè kó ẹrù ìlú náà àti àwọn ẹran ọ̀sìn rẹ̀ fún ara yín. Kí ẹ lúgọ sí ẹ̀yìn ìlú náà.”
-