-
Jóṣúà 8:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Gbàrà tí ẹ bá ti gba ìlú náà, kí ẹ dáná sun ún.+ Ohun tí Jèhófà sọ ni kí ẹ ṣe. Ẹ wò ó, mo ti pàṣẹ fún yín.”
-
-
Jóṣúà 8:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Jóṣúà wá dáná sun ìlú Áì, ó sọ ọ́ di òkìtì àwókù,+ bó sì ṣe wà nìyẹn títí dòní.
-