-
Jóṣúà 9:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Torí náà, wọ́n dá ọgbọ́n kan, wọ́n kó oúnjẹ sínú àwọn àpò tó ti gbó, wọ́n sì gbé e sórí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn, pẹ̀lú awọ tí wọ́n ń rọ wáìnì sí, tó ti gbó, tó sì ti bẹ́, àmọ́ tí wọ́n ti rán;
-