-
Jóṣúà 9:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn ìjòyè náà sì sọ pé: “Ẹ jẹ́ ká dá ẹ̀mí wọn sí, àmọ́ kí wọ́n máa bá wa ṣẹ́gi, kí wọ́n sì máa pọnmi fún gbogbo àpéjọ náà.” Ìlérí tí àwọn ìjòyè náà ṣe fún wọn nìyẹn.
-