-
Jóṣúà 6:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Nígbà náà, Jèhófà sọ fún Jóṣúà pé: “Wò ó, mo ti fi Jẹ́ríkò àti ọba rẹ̀ lé ọ lọ́wọ́, pẹ̀lú àwọn jagunjagun rẹ̀ tó lákíkanjú.+
-
-
Jóṣúà 6:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Wọ́n fi idà pa gbogbo ohun tó wà nínú ìlú náà run, wọ́n pa ọkùnrin, obìnrin, ọmọdé àti àgbà, akọ màlúù, àgùntàn àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+
-