-
Nọ́ńbà 32:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Àwa máa dira ogun,+ a ó sì máa lọ níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì títí a fi máa mú wọn dé àyè wọn, àmọ́ àwọn ọmọ wa á máa gbé inú àwọn ìlú olódi, kí àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà má bàa yọ wọ́n lẹ́nu.
-
-
Nọ́ńbà 32:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Àwọn ọmọ Gádì àti àwọn ọmọ Rúbẹ́nì wá dá Mósè lóhùn pé: “Ohun tí olúwa mi pa láṣẹ ni àwa ìránṣẹ́ rẹ máa ṣe gẹ́lẹ́.
-