-
Jóṣúà 10:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Jèhófà da àárín wọn rú níwájú Ísírẹ́lì,+ wọ́n sì pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ ní Gíbíónì, wọ́n lé wọn gba ọ̀nà tí wọ́n ń gbà gòkè lọ sí Bẹti-hórónì, wọ́n sì ń pa wọ́n títí lọ dé Ásékà àti Mákédà.
-
-
Jóṣúà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé.
-
-
Jóṣúà 15:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Gédérótì, Bẹti-dágónì, Náámà àti Mákédà,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mẹ́rìndínlógún (16), pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-