Jóṣúà 10:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà sì sọ fún Jóṣúà pé: “Má bẹ̀rù wọn,+ torí mo ti fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Ìkankan nínú wọn ò ní lè dojú kọ ọ́.”+
8 Jèhófà sì sọ fún Jóṣúà pé: “Má bẹ̀rù wọn,+ torí mo ti fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Ìkankan nínú wọn ò ní lè dojú kọ ọ́.”+