-
Jóṣúà 8:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ohun tí o ṣe sí Jẹ́ríkò àti ọba rẹ̀ gẹ́lẹ́ ni kí o ṣe sí Áì àti ọba rẹ̀,+ àmọ́ ẹ lè kó ẹrù ìlú náà àti àwọn ẹran ọ̀sìn rẹ̀ fún ara yín. Kí ẹ lúgọ sí ẹ̀yìn ìlú náà.”
-
-
Jóṣúà 8:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kó ẹran ọ̀sìn àti ẹrù ìlú náà fún ara wọn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Jóṣúà.+
-