Léfítíkù 27:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Bákan náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ ra ẹnikẹ́ni tí a máa pa run pa dà.+ Ṣe ni kí ẹ pa á.+ Jóṣúà 11:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jóṣúà gba gbogbo ìlú àwọn ọba yìí, ó sì fi idà ṣẹ́gun gbogbo ọba wọn.+ Ó pa wọ́n run,+ bí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà ṣe pa á láṣẹ. Jóṣúà 24:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “‘Lẹ́yìn náà, ẹ sọdá Jọ́dánì,+ ẹ sì dé Jẹ́ríkò.+ Àwọn olórí* ìlú Jẹ́ríkò, àwọn Ámórì, àwọn Pérísì, àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Gẹ́gáṣì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì bá yín jà, àmọ́ mo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́.+
12 Jóṣúà gba gbogbo ìlú àwọn ọba yìí, ó sì fi idà ṣẹ́gun gbogbo ọba wọn.+ Ó pa wọ́n run,+ bí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà ṣe pa á láṣẹ.
11 “‘Lẹ́yìn náà, ẹ sọdá Jọ́dánì,+ ẹ sì dé Jẹ́ríkò.+ Àwọn olórí* ìlú Jẹ́ríkò, àwọn Ámórì, àwọn Pérísì, àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Gẹ́gáṣì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì bá yín jà, àmọ́ mo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́.+