-
Jóṣúà 11:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Jóṣúà ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ yìí, agbègbè olókè, gbogbo Négébù,+ gbogbo ilẹ̀ Góṣénì, Ṣẹ́fẹ́là,+ Árábà+ àti agbègbè olókè Ísírẹ́lì àti Ṣẹ́fẹ́là rẹ̀,* 17 láti Òkè Hálákì, tó lọ dé Séírì àti títí lọ dé Baali-gádì,+ ní Àfonífojì Lẹ́bánónì, ní ìsàlẹ̀ Òkè Hámónì,+ ó mú gbogbo ọba wọn, ó ṣẹ́gun wọn, ó sì pa wọ́n.
-