Jóṣúà 10:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Jóṣúà ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ tó wà ní agbègbè olókè, Négébù, Ṣẹ́fẹ́là,+ àwọn gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àti gbogbo ọba wọn, kò ṣẹ́ ẹnì kankan kù; ó pa gbogbo ohun eléèémí run,+ bí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ṣe pa á láṣẹ gẹ́lẹ́.+ Jóṣúà 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jóṣúà ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ yìí, agbègbè olókè, gbogbo Négébù,+ gbogbo ilẹ̀ Góṣénì, Ṣẹ́fẹ́là,+ Árábà+ àti agbègbè olókè Ísírẹ́lì àti Ṣẹ́fẹ́là rẹ̀,*
40 Jóṣúà ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ tó wà ní agbègbè olókè, Négébù, Ṣẹ́fẹ́là,+ àwọn gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ àti gbogbo ọba wọn, kò ṣẹ́ ẹnì kankan kù; ó pa gbogbo ohun eléèémí run,+ bí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ṣe pa á láṣẹ gẹ́lẹ́.+
16 Jóṣúà ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ yìí, agbègbè olókè, gbogbo Négébù,+ gbogbo ilẹ̀ Góṣénì, Ṣẹ́fẹ́là,+ Árábà+ àti agbègbè olókè Ísírẹ́lì àti Ṣẹ́fẹ́là rẹ̀,*