-
Jóṣúà 11:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Lẹ́yìn náà, Jóṣúà pa dà, ó sì gba Hásórì, o fi idà pa ọba rẹ̀,+ torí pé Hásórì ni olórí gbogbo àwọn ìlú yìí tẹ́lẹ̀.