Diutarónómì 2:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Àmọ́ Síhónì ọba Hẹ́ṣíbónì kò jẹ́ ká kọjá, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ gbà á láyè pé kó ṣorí kunkun,+ kí ọkàn rẹ̀ sì le, kó lè fi í lé ọ lọ́wọ́ bó ṣe rí báyìí. +
30 Àmọ́ Síhónì ọba Hẹ́ṣíbónì kò jẹ́ ká kọjá, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ gbà á láyè pé kó ṣorí kunkun,+ kí ọkàn rẹ̀ sì le, kó lè fi í lé ọ lọ́wọ́ bó ṣe rí báyìí. +