ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 12:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Síhónì+ ọba àwọn Ámórì, tó ń gbé ní Hẹ́ṣíbónì, tó sì ń jọba láti Áróérì,+ tó wà létí Àfonífojì Áánónì+ àti láti àárín àfonífojì náà àti ìdajì Gílíádì títí dé Àfonífojì Jábókù, ààlà àwọn ọmọ Ámónì.

  • Àwọn Onídàájọ́ 11:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọba àwọn ọmọ Ámónì sọ fún àwọn tí Jẹ́fútà rán wá pé: “Torí pé nígbà tí Ísírẹ́lì kúrò ní Íjíbítì,+ wọ́n gba ilẹ̀ mi láti Áánónì+ dé Jábókù títí dé Jọ́dánì.+ Ó yá, dá a pa dà ní àlàáfíà.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́