-
Jóṣúà 6:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àwọn ọ̀dọ́kùnrin tó ṣe amí náà wọlé lọ, wọ́n sì mú Ráhábù, bàbá rẹ̀, ìyá rẹ̀, àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo èèyàn rẹ̀ jáde; àní wọ́n kó gbogbo ìdílé rẹ̀ jáde,+ wọ́n sì kó wọn wá sí ibì kan lẹ́yìn ibùdó Ísírẹ́lì, ohunkóhun ò ṣe wọ́n.
-