Nọ́ńbà 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Rán àwọn ọkùnrin lọ ṣe amí* ilẹ̀ Kénáánì tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Kí ẹ rán ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà baba ńlá wọn kọ̀ọ̀kan, kí ọ̀kọ̀ọ̀kan sì jẹ́ ìjòyè+ láàárín wọn.”+ Nọ́ńbà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 nínú ẹ̀yà Júdà, Kélẹ́bù+ ọmọ Jéfúnè;
2 “Rán àwọn ọkùnrin lọ ṣe amí* ilẹ̀ Kénáánì tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Kí ẹ rán ọkùnrin kan látinú ẹ̀yà baba ńlá wọn kọ̀ọ̀kan, kí ọ̀kọ̀ọ̀kan sì jẹ́ ìjòyè+ láàárín wọn.”+