Jóṣúà 21:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Kò sí ìlérí* tí kò ṣẹ nínú gbogbo ìlérí dáadáa tí Jèhófà ṣe fún ilé Ísírẹ́lì; gbogbo rẹ̀ ló ṣẹ pátá.+
45 Kò sí ìlérí* tí kò ṣẹ nínú gbogbo ìlérí dáadáa tí Jèhófà ṣe fún ilé Ísírẹ́lì; gbogbo rẹ̀ ló ṣẹ pátá.+