1 Àwọn Ọba 8:65 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 65 Ní àkókò yẹn, Sólómọ́nì ṣe àjọyọ̀+ náà pẹ̀lú gbogbo Ísírẹ́lì, wọ́n jẹ́ ìjọ ńlá láti Lebo-hámátì* títí dé Àfonífojì Íjíbítì,+ wọ́n wà níwájú Jèhófà Ọlọ́run wa fún ọjọ́ méje àti ọjọ́ méje míì, ó jẹ́ ọjọ́ mẹ́rìnlá (14) lápapọ̀.
65 Ní àkókò yẹn, Sólómọ́nì ṣe àjọyọ̀+ náà pẹ̀lú gbogbo Ísírẹ́lì, wọ́n jẹ́ ìjọ ńlá láti Lebo-hámátì* títí dé Àfonífojì Íjíbítì,+ wọ́n wà níwájú Jèhófà Ọlọ́run wa fún ọjọ́ méje àti ọjọ́ méje míì, ó jẹ́ ọjọ́ mẹ́rìnlá (14) lápapọ̀.