Jóṣúà 19:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kèké kejì+ wá mú Síméónì, ẹ̀yà Síméónì+ ní ìdílé-ìdílé. Ogún wọn sì wà láàárín ogún Júdà.+ 2 Ogún wọn ni Bíá-ṣébà,+ pẹ̀lú Ṣébà, Móládà,+
19 Kèké kejì+ wá mú Síméónì, ẹ̀yà Síméónì+ ní ìdílé-ìdílé. Ogún wọn sì wà láàárín ogún Júdà.+ 2 Ogún wọn ni Bíá-ṣébà,+ pẹ̀lú Ṣébà, Móládà,+