1 Kíróníkà 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn ọmọ Éfúrémù+ ni Ṣútélà,+ ọmọ* rẹ̀ ni Bérédì, ọmọ rẹ̀ ni Táhátì, ọmọ rẹ̀ ni Éléádà, ọmọ rẹ̀ ni Táhátì, 1 Kíróníkà 7:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Àwọn ibi tí wọ́n ń gbé àti ohun ìní wọn ni Bẹ́tẹ́lì+ àti àwọn àrọko* rẹ̀, Nááránì ní apá ìlà oòrùn, Gésérì ní apá ìwọ̀ oòrùn àti àwọn àrọko rẹ̀ pẹ̀lú Ṣékémù àti àwọn àrọko rẹ̀ títí dé Ááyà* àti àwọn àrọko rẹ̀;
20 Àwọn ọmọ Éfúrémù+ ni Ṣútélà,+ ọmọ* rẹ̀ ni Bérédì, ọmọ rẹ̀ ni Táhátì, ọmọ rẹ̀ ni Éléádà, ọmọ rẹ̀ ni Táhátì,
28 Àwọn ibi tí wọ́n ń gbé àti ohun ìní wọn ni Bẹ́tẹ́lì+ àti àwọn àrọko* rẹ̀, Nááránì ní apá ìlà oòrùn, Gésérì ní apá ìwọ̀ oòrùn àti àwọn àrọko rẹ̀ pẹ̀lú Ṣékémù àti àwọn àrọko rẹ̀ títí dé Ááyà* àti àwọn àrọko rẹ̀;