Àwọn Onídàájọ́ 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Lẹ́yìn náà, áńgẹ́lì Jèhófà wá, + ó sì jókòó sábẹ́ igi ńlá tó wà ní Ọ́fírà, èyí tó jẹ́ ti Jóáṣì ọmọ Abi-ésérì.+ Gídíónì+ ọmọ rẹ̀ ń pa àlìkámà* níbi tí wọ́n ti ń fún wáìnì kí àwọn ọmọ Mídíánì má bàa rí i.
11 Lẹ́yìn náà, áńgẹ́lì Jèhófà wá, + ó sì jókòó sábẹ́ igi ńlá tó wà ní Ọ́fírà, èyí tó jẹ́ ti Jóáṣì ọmọ Abi-ésérì.+ Gídíónì+ ọmọ rẹ̀ ń pa àlìkámà* níbi tí wọ́n ti ń fún wáìnì kí àwọn ọmọ Mídíánì má bàa rí i.