-
Nọ́ńbà 27:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 “Òótọ́ làwọn ọmọ Sélóféhádì sọ. Rí i pé o fún wọn ní ohun ìní tí wọ́n lè jogún láàárín àwọn arákùnrin bàbá wọn, kí o sì mú kí ogún bàbá wọn di tiwọn.+
-
-
Nọ́ńbà 27:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Tí bàbá rẹ̀ ò bá sì ní arákùnrin, kí ẹ fún mọ̀lẹ́bí rẹ̀ tó sún mọ́ ọn jù ní ogún rẹ̀, yóò sì di tirẹ̀. Èyí ni àṣẹ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì á máa tẹ̀ lé láti ṣèdájọ́, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè gẹ́lẹ́.’”
-