-
Nọ́ńbà 36:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ohun tí Jèhófà sọ nípa àwọn ọmọbìnrin Sélóféhádì ni pé: ‘Wọ́n lè fẹ́ ẹni tó bá wù wọ́n. Àmọ́, inú ìdílé tó wá látinú ẹ̀yà bàbá wọn ni kí wọ́n ti fẹ́ ẹ.
-
-
Nọ́ńbà 36:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Wọ́n lọ́kọ nínú ìdílé Mánásè ọmọ Jósẹ́fù, kí ogún wọn má bàa kúrò nínú ẹ̀yà ìdílé bàbá wọn.
-