-
Nọ́ńbà 26:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ìwọ̀nyí ni ìdílé Mánásè, iye àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìléláàádọ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún méje (52,700).+
-
-
Nọ́ńbà 26:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Éfúrémù, iye àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélọ́gbọ̀n ó lé ọgọ́rùn-ún márùn-ún (32,500).+ Èyí ni àwọn ọmọ Jósẹ́fù ní ìdílé-ìdílé.
-