-
Jóṣúà 10:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Bí wọ́n ṣe ń sá fún Ísírẹ́lì, tí wọ́n sì wà níbi gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Bẹti-hórónì, Jèhófà rọ̀jò òkúta yìnyín ńláńlá lé wọn lórí láti ọ̀run, ó ń rọ̀ lé wọn lórí títí dé Ásékà, wọ́n sì ṣègbé. Kódà, àwọn tí yìnyín náà pa pọ̀ ju àwọn tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi idà pa lọ.
-
-
Jóṣúà 21:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Wọ́n fi kèké pín àwọn ìlú fún àwọn ìdílé ọmọ Kóhátì yòókù nínú àwọn ọmọ Léfì látinú ìpín ẹ̀yà Éfúrémù.
-
-
Jóṣúà 21:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Kíbúsáímù pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Bẹti-hórónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú mẹ́rin.
-