Jóṣúà 15:63 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Àmọ́ àwọn ọkùnrin Júdà kò lè lé àwọn ará Jébúsì+ tó ń gbé Jerúsálẹ́mù+ lọ,+ torí náà àwọn ará Jébúsì ṣì ń gbé pẹ̀lú àwọn èèyàn Júdà ní Jerúsálẹ́mù títí di òní yìí.
63 Àmọ́ àwọn ọkùnrin Júdà kò lè lé àwọn ará Jébúsì+ tó ń gbé Jerúsálẹ́mù+ lọ,+ torí náà àwọn ará Jébúsì ṣì ń gbé pẹ̀lú àwọn èèyàn Júdà ní Jerúsálẹ́mù títí di òní yìí.