-
Jóṣúà 15:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn ìlú tó wà ní ìkángun ẹ̀yà Júdà lápá ibi tí ààlà Édómù+ wà ní gúúsù nìyí: Kábúséélì, Édérì, Jágúrì,
-
-
Jóṣúà 15:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Lẹ́báótì, Ṣílíhímù, Áyínì àti Rímónì,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29), pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-