-
Jóṣúà 21:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
-
-
Jóṣúà 21:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Jámútì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Ẹ́ń-gánímù pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú mẹ́rin.
-