Jóṣúà 21:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Látinú ìpín ẹ̀yà Náfútálì: ìlú ààbò+ tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ, ìyẹn Kédéṣì+ ní Gálílì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Hamoti-dórì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Kátánì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú mẹ́ta.
32 Látinú ìpín ẹ̀yà Náfútálì: ìlú ààbò+ tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ, ìyẹn Kédéṣì+ ní Gálílì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Hamoti-dórì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Kátánì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, ó jẹ́ ìlú mẹ́ta.