ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 11:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Lẹ́yìn náà, Jóṣúà pa dà, ó sì gba Hásórì, o fi idà pa ọba rẹ̀,+ torí pé Hásórì ni olórí gbogbo àwọn ìlú yìí tẹ́lẹ̀.

  • Àwọn Onídàájọ́ 4:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Torí náà, Jèhófà fi wọ́n lé ọwọ́ Jábínì ọba Kénáánì,+ tó jọba ní Hásórì. Sísérà ni olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀, ó sì ń gbé ní Háróṣétì+ ti àwọn orílẹ̀-èdè.*

  • 1 Sámúẹ́lì 12:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àmọ́ wọ́n gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run wọn, ó sì tà wọ́n+ sọ́wọ́ Sísérà+ olórí àwọn ọmọ ogun Hásórì àti sọ́wọ́ àwọn Filísínì+ àti sọ́wọ́ ọba Móábù,+ wọ́n sì bá wọn jà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́