-
Jóṣúà 18:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àwọn ọkùnrin náà múra láti lọ, Jóṣúà sì pàṣẹ fún àwọn tó máa ṣètò bí wọ́n á ṣe pín ilẹ̀ náà pé: “Ẹ lọ rìn káàkiri ilẹ̀ náà, kí ẹ ṣètò bí ẹ ṣe máa pín in, kí ẹ wá pa dà sọ́dọ̀ mi, màá sì ṣẹ́ kèké lé e níbí fún yín níwájú Jèhófà ní Ṣílò.”+
-