-
Nọ́ńbà 35:26, 27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 “‘Àmọ́ tí apààyàn náà bá kọjá ààlà ìlú ààbò rẹ̀ tó sá wọ̀, 27 tí ẹni tó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ sì rí i lẹ́yìn ààlà ìlú ààbò rẹ̀, tó sì pa á, kò jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀.
-