Jóṣúà 14:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kiriati-ábà+ ni Hébúrónì ń jẹ́ tẹ́lẹ̀ (Ábà jẹ́ ẹni ńlá láàárín àwọn Ánákímù). Ogun sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ náà.+ Jóṣúà 21:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n fún àwọn ọmọ àlùfáà Áárónì ní ìlú ààbò tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ,+ ìyẹn Hébúrónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Líbínà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,
15 Kiriati-ábà+ ni Hébúrónì ń jẹ́ tẹ́lẹ̀ (Ábà jẹ́ ẹni ńlá láàárín àwọn Ánákímù). Ogun sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ náà.+
13 Wọ́n fún àwọn ọmọ àlùfáà Áárónì ní ìlú ààbò tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ,+ ìyẹn Hébúrónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Líbínà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,