-
1 Kíróníkà 6:63Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
63 Wọ́n ṣẹ́ kèké, wọ́n sì fún àwọn ọmọ Mérárì àti àwọn ìdílé wọn ní ìlú méjìlá (12) látinú ẹ̀yà Rúbẹ́nì, ẹ̀yà Gádì àti ẹ̀yà Sébúlúnì.+
-