Jóṣúà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé. Jóṣúà 15:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Góṣénì,+ Hólónì àti Gílò,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú mọ́kànlá (11), pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.