Jóṣúà 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ wọn ò lé àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Gésérì+ kúrò, àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé láàárín Éfúrémù títí di òní yìí,+ wọ́n sì ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.+
10 Àmọ́ wọn ò lé àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Gésérì+ kúrò, àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé láàárín Éfúrémù títí di òní yìí,+ wọ́n sì ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.+