Jóṣúà 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà wá sọ fún Jóṣúà pé: “Òní yìí ni mo máa bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ọ ga níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì,+ kí wọ́n lè mọ̀ pé màá wà pẹ̀lú rẹ+ bí mo ṣe wà pẹ̀lú Mósè.+
7 Jèhófà wá sọ fún Jóṣúà pé: “Òní yìí ni mo máa bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ọ ga níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì,+ kí wọ́n lè mọ̀ pé màá wà pẹ̀lú rẹ+ bí mo ṣe wà pẹ̀lú Mósè.+