78 láti ara ilẹ̀ ẹ̀yà Rúbẹ́nì tó wà ní agbègbè ilẹ̀ Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò títí dé apá ìlà oòrùn Jọ́dánì, wọ́n fún wọn ní Bésérì tó wà ní aginjù pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Jáhásì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, 79 Kédémótì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Mẹ́fáátì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀;