ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 6:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Rí i pé o fi àwọn ọ̀rọ̀ yìí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí sọ́kàn,

  • Diutarónómì 12:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Gbogbo ọ̀rọ̀ tí mò ń pa láṣẹ fún yín ni kí ẹ rí i pé ẹ tẹ̀ lé.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi kún un, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ yọ kúrò nínú rẹ̀.+

  • 2 Àwọn Ọba 21:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Mi ò tún ní mú kí Ísírẹ́lì rìn gbéregbère kúrò ní ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá wọn,+ tí wọ́n bá ṣáà ti rí i pé wọ́n tẹ̀ lé gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún wọn,+ ìyẹn gbogbo Òfin tí Mósè ìránṣẹ́ mi pa láṣẹ fún wọn pé kí wọ́n máa tẹ̀ lé.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́