Nọ́ńbà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn yìí ni wọ́n pè látinú àpéjọ náà. Wọ́n jẹ́ ìjòyè+ nínú ẹ̀yà àwọn bàbá wọn, olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ní Ísírẹ́lì.”+ Diutarónómì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ yan àwọn ọkùnrin tó jẹ́ ọlọ́gbọ́n àti olóye, tí wọ́n sì ní ìrírí látinú àwọn ẹ̀yà yín, màá sì fi wọ́n ṣe olórí yín.’+
16 Àwọn yìí ni wọ́n pè látinú àpéjọ náà. Wọ́n jẹ́ ìjòyè+ nínú ẹ̀yà àwọn bàbá wọn, olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ní Ísírẹ́lì.”+
13 Ẹ yan àwọn ọkùnrin tó jẹ́ ọlọ́gbọ́n àti olóye, tí wọ́n sì ní ìrírí látinú àwọn ẹ̀yà yín, màá sì fi wọ́n ṣe olórí yín.’+