-
Jóṣúà 24:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Jóṣúà sì sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ wò ó! Òkúta yìí máa jẹ́ ẹ̀rí lòdì sí wa,+ torí ó ti gbọ́ gbogbo ohun tí Jèhófà bá wa sọ, ó sì máa jẹ́ ẹ̀rí lòdì sí yín, kí ẹ má bàa sẹ́ Ọlọ́run yín.”
-