-
Diutarónómì 31:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ẹ kó gbogbo àgbààgbà ẹ̀yà yín àti àwọn olórí yín jọ sọ́dọ̀ mi, kí n lè fi àwọn ọ̀rọ̀ yìí tó wọn létí, kí n sì fi ọ̀run àti ayé ṣe ẹlẹ́rìí lòdì sí wọn.+
-