Jóṣúà 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jóṣúà wá ṣẹ́ kèké fún wọn ní Ṣílò níwájú Jèhófà.+ Ibẹ̀ ni Jóṣúà ti pín ilẹ̀ náà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn.+
10 Jóṣúà wá ṣẹ́ kèké fún wọn ní Ṣílò níwájú Jèhófà.+ Ibẹ̀ ni Jóṣúà ti pín ilẹ̀ náà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn.+