Àwọn Onídàájọ́ 2:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jóṣúà ọmọ Núnì, ìránṣẹ́ Jèhófà, wá kú lẹ́ni àádọ́fà (110) ọdún.+ 9 Torí náà, wọ́n sin ín sí ilẹ̀ tó jogún ní Timunati-hérésì,+ èyí tó wà ní agbègbè olókè Éfúrémù, ní àríwá Òkè Gááṣì.+
8 Jóṣúà ọmọ Núnì, ìránṣẹ́ Jèhófà, wá kú lẹ́ni àádọ́fà (110) ọdún.+ 9 Torí náà, wọ́n sin ín sí ilẹ̀ tó jogún ní Timunati-hérésì,+ èyí tó wà ní agbègbè olókè Éfúrémù, ní àríwá Òkè Gááṣì.+