-
Nọ́ńbà 9:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ní ìrọ̀lẹ́* ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní, wọ́n ṣètò ẹbọ Ìrékọjá náà ní aginjù Sínáì. Gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ fún Mósè ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe.
-