ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 2:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Torí náà, Jèhófà máa ń yan àwọn onídàájọ́ tó máa gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tó ń kó wọn lẹ́rù.+

  • Àwọn Onídàájọ́ 2:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nígbàkigbà tí Jèhófà bá yan àwọn onídàájọ́ fún wọn,+ Jèhófà máa ń wà pẹ̀lú onídàájọ́ náà, ó sì máa ń gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn ní gbogbo ọjọ́ tí onídàájọ́ náà bá fi wà; Jèhófà ṣàánú wọn*+ torí pé àwọn tó ń ni wọ́n lára+ àtàwọn tó ń fìyà jẹ wọ́n mú kí wọ́n máa kérora.

  • Àwọn Onídàájọ́ 3:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá ké pe Jèhófà pé kó ran àwọn lọ́wọ́,+ torí náà, Jèhófà yan ẹnì kan tó máa gbà wọ́n sílẹ̀,+ ìyẹn Éhúdù+ ọmọ Gérà, ọmọ Bẹ́ńjámínì,+ ọkùnrin tó ń lo ọwọ́ òsì.+ Nígbà tó yá, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi ìṣákọ́lẹ̀* rán an sí Ẹ́gílónì ọba Móábù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́