1 Kíróníkà 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àwọn ọmọ Kénásì ni Ótíníẹ́lì+ àti Seráyà, ọmọ* Ótíníẹ́lì sì ni Hátátì.