-
Léfítíkù 26:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ó dájú pé ẹ máa lé àwọn ọ̀tá yín, ẹ ó sì fi idà ṣẹ́gun wọn. 8 Ẹ̀yin márùn-ún yóò lé ọgọ́rùn-ún (100), ẹ̀yin ọgọ́rùn-ún (100) yóò lé ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000), ẹ ó sì fi idà ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá yín.+
-